Thursday, January 1, 2015

IFA NI KASOPE, KASOPE

IFA NI KASOPE, KASOPE

MO NI KASOPE KASOPE

IFA NI KOMO EKU O SOPE

OMO EKU LOHUN LOPE DA

IYAN LOMO ARAYE NFI OMO EKU JE

IFA NI KASOPE KASOPE

MO NI KASOPE KASOPE

IFA NI KOMO ERAN O SOPE

OMO ERAN LOHUN O LOPE DA

IYAN LOMO ARAYE N FOMO ERAN JE

IFA NI KASOPE KASOPE

MO NI KASOPE KASOPE

IFA NI KOMO EYE O SOPE

OMO EYE LOHUN O LOPE DA

IYAN LOMO ARAYE N FOMO EYE JE

IFA NI KASOPE KASOPE

MO NI KASOPE KASOPE

IFA NI KOMO EJA O SOPE

OMO EJA LOHUN LOPE DA

IYAN LOMO ARAYE N FOMO EJA JE

IFA NI KASOPE KASOPE

MO NI KASOPE KASOPE

IFA NI KOMO ENIYAN O SOPE

OMO ENIYAN NIKAN LO MOPE DA

OMO ENIYAN NIKAN LOMORE

WON RIN KOTO LORIN AWO BO SI WON LENU

WON ; MO WA DUPE TEMI

MO WA DUPE TEMI BI A BA SENI LORE OPE LA N DU

MO WA DUPE TEMI. ESE PUPO ALAGBA OJO
ifa0



IFA NI KASOPE, KASOPE

No comments:

Post a Comment