Wednesday, February 18, 2015

Anu opolopo obinrin si se mi lojo oni !

Hunmmmmmm, Ẹ ku ọsan o, e ku ataaro o, o ga o, anu opolopo obinrin si se mi lojo oni, nitori opolopo ninu won lo ti so aponle ara re nu niti tori eja #300 ati hi malt #100, tabi tori aso #1,500 won ni awon nse ayajo ololufe. Awon oponu ayirada nigba ti o si je pe opolopo ni ko mowe ti won ya olodo kale, e lo wo itumo valentine dada ki e mo itu mo re ni odoodun ni awon okunrin fi nba aye awon obinrin je sibesibe won o gbon ni. Nigbati kosi si iberu olohun lara gbogbo wa.
worried_african_woman

Sebi won ni iberu olohun ni iplese ogbon, e je ki gbogbo wa beru olohun. Ki awa naa le ni ayo okan, olomo kan wa po lo bisu ewura, e wa ni awon okunrin gidi kife olomo kan talo ma ri agbebo edie loja to ma kowo le, e je ka sora ki a ma tori ede ba ode je. Oro mi ko po, die to fun ologbon eniyan. Ire ooo

No comments:

Post a Comment